Skip to content

YORUBA COUNCIL OF YOUTH WORLDWIDE (YCYW) OGUN STATE COUNCIL KI MAMA WA HER EXCELLENCY, ENGINEER( MRS) NAIMOT SALAKO (DEPUTY GOVERNOR) KU AYEYE OJO IBI WON

Ni Orúkọ Gbogbo Igbimọ Ọdọ Yorùbá Lágbayé ẹka tí Ipinlẹ Ogun labẹ Àṣẹ Alaga wa Hon. Sunday Adebowale a ki Mama wa, Mama rere, Her Excellency Engineer (Mrs) Naimot Salako. (Deputy Governor) ku ayẹyẹ ọjọ ìbí wọn loni ọjọ kejo (8), Oṣu kini (January), ọdún okanlelogun le ni ọgọrun meji (2022).

A si gba ni adura npe ki ọlọrun tún bọ máa b’awa lọra ẹmi yin ninu ọlá, ninu ipo, ninu ọgbọn àti oye ti ẹ fi tunbọ máa ṣe ìlú ipinlẹ Ogun lọ síwájú si, paapa julọ ninu àìkú baálẹ̀ ọrọ.

Lẹẹkan si ẹku oriire ọjọ ibi, ẹmi yin a ṣe púpọ ọdún láyé, lágbára ọlọrun àti àwọn tó tẹ ilẹ yorùbá dó. Àṣẹ!

A si tun fi akoko yi dupẹ lọwọ yin Lẹẹkansi fún ipa ribiribi ti ẹ tì nko l’agbo òṣèlú ati ìdàgbàsókè ipinlẹ Ogun, paapa julọ ni ẹka ti idagbasoke awọn ọdọ ipinlẹ Ogun ati gbogbo orilẹ-ède Naijiria lapapọ, ẹ ṣe gan adupẹ, ki ọlọrun bawa kun yin lọwọ

Ọmọ Yorùbá ni mí, Ọmọ kaarọ ojiire!

Fún igbimọ ọdọ ipinlẹ ogun,

E-signed:

Hon. Sunday Adebowale
Chairman, YCYW Ogun State Council


Asiwaju Oloko Saheed
Gen. Secretary, YCYW Ogun State Council.

Comr Yusuf Wasiu Olamilekan
(Oko Momi)
Publicity Secretary.
Ycywogunstate@gmail.com
8/1/2022

Leave a Reply

Please log in using one of these methods to post your comment:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google photo

You are commenting using your Google account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

Connecting to %s

%d bloggers like this: