Skip to content

YORUBA COUNCIL OF YOUTH WORLDWIDE YCYW EKA TI IPINLE OGUN KI KABIESI AKARIGBO TI ILU RẸMỌ KU ORIIRE OJO IBI

Ni Orúkọ Gbogbo Igbimọ Ọdọ Yorùbá Lágbayé ẹka tí Ipinlẹ Ogun labẹ Àṣẹ Alaga wa Hon. Sunday Adebowale a ki Kabiesi Alayeluwa Oba Babatunde Victor Adewale Ajayi ( The Akarigbo and Paramount Ruler of Remo Land, Ogun State) ku ayẹyẹ ọjọ ìbí wọn loni ọjọ kàrún (5), oṣù kejìlá (December), ọdún okòó le ni ọgọrun meji (2021).

A si gba ni adura npe ki ọlọrun tún bọ máa b’awa lọra ẹmi kabiesi ninu ọlá, ninu ọgbọn àti oye, paapa julọ ninu àìkú baálẹ̀ ọrọ ti wọn máa fi lo itẹ awọn babanla wọn pẹ kanrin kese.

A sì tún ki gbogbo awọn ọmọ bíbí ìlú Remo, paapajulọ gbogbo ọmọ ipinlẹ Ogun, ku pọpọṣinṣin ọjọ ìbí kabiesi.

Kabiesi ìgbà yin a tunbọ máa tú wa lara o, Lẹẹkansi eku oríire, ẹmi yin aṣe púpọ odun láyé, láàyè ati láyè ire, awọn alaalẹ ìlú Remo a dúró tí yin oo. Kaaaabiesi ooo

Ọmọ Yorùbá ni mí, Ọmọ kaarọ ojiire!

E-signed:

Hon. Sunday Adebowale
Chairman, YCYW Ogun State Council

Through:

Asiwaju Oloko Saheed.
Gen. Secretary, YCYW Ogun State Council.
Ycywogunstate@gmail.com
5/12/2021.

Leave a Reply

Please log in using one of these methods to post your comment:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google photo

You are commenting using your Google account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

Connecting to %s

%d bloggers like this: