Skip to content

YORUBA COUNCIL OF YOUTHS WORLDWIDE (YCYW )OGUN STATE COUNCIL, KI MAMA WA HON (CHIEF) EFUWAPE FUNMILAYO (OGUN STATE HONOURABLE COMMISSIONER FOR WOMEN AFFAIRS AND SOCIAL WELFARE) KU ORÍIRE ỌJỌ IBI WỌ́N LÓNÌ

Ni Orúkọ Gbogbọ Igbimọ Ọdọ Yorùbá Lágbayé ẹka tí Ipinlẹ Ogun labẹ Àṣẹ Alaga wa Hon. Sunday Adebowale a ki Mama wa Hon (Chief) Efuwape Funmilayo( Ogun state Honourable Commissioner for Women affairs and Social Welfare) ku ayẹyẹ ọjọ ìbí wọn loni ọjọ keje Oṣu kẹwa(October), ọdún ọ̀kan-le-ni-okòó le ni ẹgbàá (2021)

A si gba ni adura npe ki ọlọrun tún bọ máa b’awa lọra ẹmi yin ninu ọlá, ninu ipo, ninu ọgbọn àti oye, paapa julọ ninu àìkú baálẹ̀ ọrọ. ọdọọdún làá nri orógbó, ọdọọdún làá nri arẹsà, ọdọọdún làá nri ọmọ obi lori atẹ, ọdọọdún la o maa ri yin ba, t’ẹbi, t’ara ati ojulumọ

Lẹẹkansi ẹku oriire ọjọ ibi yin loni, ẹmi yin aṣe púpọ ọdún láyé, lágbára ọlọrun àti àwọn tó tẹ ilẹ yorùbá dó. Àṣẹ!

A si tun fi akoko yi dupẹ lọwọ yin Lẹẹkansi fún ipa ribiribi ti ẹtì nko ninu ìdàgbàsókè, iṣọkan ati ìgbéga ipinle Ogun state ,ilẹ Yorùbá ati gbogbo orilẹ-ède Naijiria lapapọ paapajulọ ni ẹka awon obinrin inpinle ogun,ẹ ṣe gan adupẹ, ki ọlọrun bawa kun yin lọwọ

Omo afilekebi

Ọmọ Yorùbá ni mí, Ọmọ kaarọ ojiire!

Fún igbimọ ọdọ ipinlẹ ogunE-signed

Hon. Sunday Adebowale
Chairman, YCYW Ogun State Council

Asiwaju Oloko Saheed
Secretary, YCYW Ogun state council
7/10/2021

Leave a Reply

Please log in using one of these methods to post your comment:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google photo

You are commenting using your Google account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

Connecting to %s

%d bloggers like this: